1 Forbes láìpẹ́ yìí dárúkọ Swídìn gẹ́gẹ́bí orílẹ̀-èdè tó dára jùlọ láyé lati s’òwò – ilẹ̀ ọlọ́ràá fún àwọn olùfowopamọ́

2 Swídìn ni pà kápítà GDP Dọ́là Ẹgbẹ̀rún Mẹ́tàdinlọ́gọ́ta, Ó dín Mẹ́rinlélógójì ($56,956) tó sì ni idiwọ̀n igbé ayé tó ga jùlọ nibiki láyé

3 Isúná owó díjítà tó ga jùlọ ni Yúrópù ati ilú tó tayọ láàárín agbègbè náà ní ti àìmálo owó

4 Ìfihan Ìdije Kárí-ayé ti to Swídìn gẹ́gẹ́bi orilẹ̀-èdè tí ètò ìsúná rẹ̀ ni ìdíje jùlọ láyé

5 Swídìn ni a mọ̀ sí orilẹ̀-èdè EU tí ó ndá nǹkan silẹ̀ jùlọ, pẹ̀lú nọ́mbà pétẹ́ntì pà kápítà tó ga jùlọ

6 Swídìn wà ní ipò tó dára ju orílẹ̀-èdè míràn lọ láti músẹ àwọn Ìlepa Ìdàgbàsókè Ọlọ́jọ́pípẹ ti UN

ŃJÙMỌ̀SỌ̀RỌ̀

 • Ìdásilẹ̀ Ilé-Isẹ́
 • Imọ̀ràn nipa owó|Pípinu Owó-Ori
 • Àwọn Ànfààni Dídàgbà
 • Ìtúpalẹ̀ iye òsisẹ́
 • Ìsàkóso/Yiyàn IT
 • Àwọn òfin ati ìlàna
 • Lílò ní kíkun ọgbọ́n itajà
 • Gbígbé orísun isẹ́ ọ́físì sita
 • Ìjáfáfá Isẹ́-sise
 • Ìsàkóso ewu

ÌTÚPALẸ ỌJÀ

 • Àmi ìmoye ati ìjádesíta
 • Àwọn ilé-isẹ́ ìsòwò
 • Àsọtẹ́lẹ̀ gbogbo-gbòò
 • Àwọn ọjà olùmúlò
 • Gbígbajúmọ̀ iye-ara-ilú
 • Pínpin ọjà sí ìsọ̀rí
 • Ìdìbò èrò àwọn ará-ìlú
 • Títà ti àwọn ọjà/isẹ́

ÌWÁDÌÍ

 • Ìwífún-ni ìsòwò
 • Àwọn ìjábọ̀ ilé-isẹ́
 • Wíwà ati fífàyọ détà
 • Ibi-ìpamọ́ ọlọ́jọ́pípẹ́ Ìjọba
 • Àwọn Ìjábọ̀ Ìtọ̀lẹ́sẹ̀
 • Ìtọpinpin Mídíà
 • Détà onítùúpalẹ̀ ti orílẹ̀-èdè
 • Gbígbanisísẹ́|Wíwá òsisẹ́

ỌFÍSÌ AFOJÚUNÚSE

 • Àdírẹ́sì ilé-isẹ́ ni Stọ́kọ́mù/Swídìn
 • Nọ́mbà ẹ̀rọ-ìbánisọ̀rọ̀ pẹ̀lú ibùdó ìpè
 • Fifi méélì ránsẹ́ káàkiri ayé
 • Àtìlẹhìn oníbàárà 24/7

ÌTUMỌ̀

 • Sí/láti àádọ̀rin èdè ati jù bẹ́ẹ̀ lọ
 • Ọ̀jọ̀gbọ́n, ọmọ-onílẹ̀, akọ́sẹ́mọsẹ́ amòye-èdè
 • ISO 17100 ẹ̀rí ìmúyẹ

0
AWỌN ỌDÚN NINÚ ÌSÒWÒ NÁÀ
0
ÀWỌN ẸNIKEJI Ọ̀JỌ̀GBỌ́N
0
ÀWỌN ONIBÀÁRÀ TÓ PEGEDÉ
0
%
Ẹ̀RÍ ÌTẸNILỌ́RÙN
Àsà Àwọn ÌtánsòroOníbàárà kọ̀ọ̀kan ló yàtọ̀ – Isẹ́ àkànse kọ̀ọ̀kan ló yàtọ̀ – Ìdí nìyẹn ti a fi ngbìyànjú lati fún yín ni àsà àwọn ìtànsòro, lati bá àìní ati ifójúsùn rẹ tí kò lẹ́gbẹ́ pàdéÌmọ̀ abẹ́léÀsopọ̀ tímọ́tímọ́ wa pẹ̀lú àwọn ẹ̀ka ilé-isẹ́ ìjọba Swedish, àwọn ilé-ẹ̀kọ́ ati àwọn ilé-isẹ́ nràn wa lọ́wọ́ láti tánsòro rẹ kíákíá ati pẹ̀lú ìrọ̀rùnLo Ànfààni Kíkọ́sẹ́mọsẹ́ WaJẹ́ká fún ọ ni àtilẹhìn láti s’àseyọri – Àwọn àwòsínú ti a ti kójọ lọ́pọ̀lọpọ̀ ọdún sẹ́hin jẹ́ kọ́kọ́rọ́ sí àseyọri wa ni SwedenÀwọn ìdiwọn ati àwòsínúÀwọn ìlànà ati ìse tí a dá-lábàá ló ní àwọn ọnà lati diwọ̀n ìyọrísí tí wọn ni lórí àwọn àfojúsùn isòwò ati itajà rẹIsẹ́ ÌtayọÀwọn èsì wa ní àsopọ̀ tààrà sí dídára sí àwọn isẹ́ wa, ati paríparí sí àseyọrí rẹ – A wà níbí láti ràn ọ́ lọ́wọ́ ni gbogbo ọ̀nà

Ìròhìn tuntun

Jẹ́k’á s’àwárí gbogbo ohun tó seése!

Kàn sí wa
láti sàwári díẹ̀ sii


Frejgatan 13
114 79 Stockholm
Swídìn


+46 8 55 11 07 00
+46 8 55 11 07 01