CELanguageCE Swídìn • A nran awọn oníbàárà lọwọ káàkiri àgbáyé lati sàyípo ilẹ̀ ìsòwò Swídìsh

CE Swídìn • A nran awọn oníbàárà lọwọ káàkiri àgbáyé lati sàyípo ilẹ̀ ìsòwò Swídìsh

Innehållsförteckning

Ẹ k’áàbọ̀ sí CE Swídìn

A nran awọn oníbàárà lọwọ káàkiri àgbáyé lati sàyípo ilẹ̀ ìsòwò Swídìsh. Àwọn alájùmọ̀sọ̀rọ̀ wa fi asikò silẹ̀ lati ni ìmọ̀ dáradára nipa ilé-isẹ́ rẹ, àwọn ẹ̀rọ ati àwọn àfojúsùn ilé-isẹ́. Àwọn itánsòro ti a fifún yin yóò bá awọn ohun tí ẹ nílò aláìlẹ́gbẹ́ mu.

Swídìn jẹ́ orilẹ̀-èdè tó dàgbà gidigidi tó sì lérè pẹ̀lú ànfààní àilópin – ibi tó pé fún ọ láti wà lágbàáyé ki o si se àwári àwọn ọjà tuntun.

Jẹ́ alábàásisẹpọ̀ pẹ̀lú wa. A dúró sinsin láti tọ yin sọna ni ọ̀nà gbogbo.

 • Forbes láìpẹ́ yìí dárúkọ Swídìn gẹ́gẹ́bí orílẹ̀-èdè tó dára jùlọ láyé lati s’òwò – ilẹ̀ ọlọ́ràá fún àwọn olùfowopamọ́
 • Swídìn ni pà kápítà GDP Dọ́là Ẹgbẹ̀rún Mẹ́tàdinlọ́gọ́ta, Ó dín Mẹ́rinlélógójì ($56,956) tó sì ni idiwọ̀n igbé ayé tó ga jùlọ nibiki láyé
 • Isúná owó díjítà tó ga jùlọ ni Yúrópù ati ilú tó tayọ láàárín agbègbè náà ní ti àìmálo owó
 • Ìfihan Ìdije Kárí-ayé ti to Swídìn gẹ́gẹ́bi orilẹ̀-èdè tí ètò ìsúná rẹ̀ ni ìdíje jùlọ láyé
 • Sweden ni a mọ̀ sí orilẹ̀-èdè EU tí ó ndá nǹkan silẹ̀ jùlọ, pẹ̀lú nọ́mbà pétẹ́ntì pà kápítà tó ga jùlọ
 • Sweden wà ní ipò tó dára ju orílẹ̀-èdè míràn lọ láti músẹ àwọn Ìlepa Ìdàgbàsókè Ọlọ́jọ́pípẹ ti UN

Ńjùmọ̀sọ̀rọ̀-pẹlú
ìmọràn amòye

 • Àtìlẹhìn ìsòwò
 • Ìsòwò ati títà
 • Ìdásílẹ̀ Ilé-Is̀ẹ́
 • Àwọn Ètò Ìdàgbàsókè
 • Imọ̀ràn owó
 • Òsìsẹ́
 • Ìsàkóso Ìwífun-ni Ìmọ-ẹ̀rọ
 • Àwọn òfin ati ìlànà
 • Àwọn ìlànà títajà
 • Gbigbé isẹ́-ọ́fisi fun alágbàse
 • Isẹ́-síse dáradára
 • Itẹ̀siwájú ìsesí
 • Ìsàkóso ewu

Ọjà
àtúpalẹ̀

 • Ìgbéléwọ̀n ìpolówó ọjà
 • Ìmòye àmì/fífí-síta
 • Àwọn ilé-isẹ́ ti ìsòwò
 • Àsọtẹ́lẹ̀ Gbogbo-gbòò
 • Àwọn ọjà olùmúlò
 • Gbígbajúmọ̀ Iye Èniyàn
 • Àtúpalẹ̀ Ìwà-Ìsòtítọ́
 • Pípin Ọjà
 • Iwádí Ifowólélóri
 • Àwọn ọjà/isẹ́ síse tí yóò-tọ́
 • Èrò ìdìbò ará-ìlú
 • Àwọn ìwádìí ìtẹ́nilọ́rùn

Ìwádìí
ìtọ̀lẹ́sẹ̀

 • Ìwífún-ni Ìsòwò
 • Àwọn Ìjábọ̀ Ilé-Isẹ́
 • Ńwa’lẹ̀ détà
 • Àkọsílẹ̀ àkójọpọ̀ détà
 • Àwọn àtòkọ Ímeelì
 • Àwọn ibi-ìpamọ́ ọlọ́jọ́pipẹ́ Ìjọba
 • Àwọn Ìjábọ̀ Ìtọ̀lẹ́sẹ̀
 • Ìran ìsáájú
 • Ìtọpinpin Mídíà
 • Ìròhìn|Àwọn àtẹ̀jáde Oníròhìn
 • Gbígbà-sẹ́nu-isẹ́|Dọdẹ-àwọn ti a fẹ gbà sísẹ́
 • Détà onítùúpalẹ̀
 • Àwọn ìwé funfun

Ìtumọ̀
àwọn isẹ́ èdè

 • Àádọ́rin-ó-lé àwọn èdè
 • Ọlọ́pọ̀èdè DTP
 • Ọ̀jọ̀gbọ́́n amòye-èdè
 • Kíkà-àmúdájú ati sísàtúnse
 • Ìdánilójú àmúyẹ
 • Ẹ̀̀yà àìrídìmú ti ágbègbè
 • Àwọn ìgbésílẹ̀ kíákíá
 • Ìsàkóso ìpèlórúkọ
 • Mímú ọ̀rọ̀ tàbí ìhìn kan dọ́gba lati èdè kan si èdè miran láìsí ìyípadà
 • Dída ìwé kọ
 • Kíkọ àkọlé fíìmù fídíò ojú-òpó wẹ́ẹ̀bù
 • Sísọdi t’agbègbè òpó wẹ́ẹ́bù

Àfojúunúse
ọ́físì swídísh

 • Àdírẹ̀sì Ilé-Isẹ́
 • Nọ́mbà ẹ̀rọ-ìbánisọ̀rọ̀
 • Àtìlẹhìn Oníbàárà
 • Ìbùdó Ìpè
 • Fífí ìpè sọwọ́sìwájú
 • Fífí méélì sọwọ́sìwájú
 • Olùgbàlejò tí nsisẹ́
 • Ìfọ̀rọ̀jẹ̀wọ̀ wẹ́ẹ́bù tí nsisẹ́
 • Yiyan àkókò fún ìpàdé
 • Ńsisẹ́ lóri àsẹ
 • Àwọn isẹ́ àbójútó

Àsà Àwọn Ìtánsòro

Oníbàárà kọ̀ọ̀kan ló yàtọ̀ – Isẹ́ àkànse kọ̀ọ̀kan ló yàtọ̀ – Ìdí nìyẹn ti a fi ngbìyànjú lati fún yín ni àsà àwọn ìtànsòro, lati bá àìní ati ifójúsùn rẹ tí kò lẹ́gbẹ́ pàdé

Ìmọ̀ abẹ́lé

Àsopọ̀ tímọ́tímọ́ wa pẹ̀lú àwọn ẹ̀ka ilé-isẹ́ ìjọba Swedish, àwọn ilé-ẹ̀kọ́ ati àwọn ilé-isẹ́ nràn wa lọ́wọ́ láti tánsòro rẹ kíákíá ati pẹ̀lú ìrọ̀rùn

Lo Ànfààni Kíkọ́sẹ́mọsẹ́ Wa

Jẹ́ká fún ọ ni àtilẹhìn láti s’àseyọri – Àwọn àwòsínú ti a ti kójọ lọ́pọ̀lọpọ̀ ọdún sẹ́hin jẹ́ kọ́kọ́rọ́ sí àseyọri wa ni Sweden

Àwọn ìdiwọn ati àwòsínú

Àwọn ìlànà ati ìse tí a dá-lábàá ló ní àwọn ọnà lati diwọ̀n ìyọrísí tí wọn ni lórí àwọn àfojúsùn isòwò ati itajà rẹ

Isẹ́ Ìtayọ

Àwọn èsì wa ní àsopọ̀ tààrà sí dídára sí àwọn isẹ́ wa, ati paríparí sí àseyọrí rẹ – A wà níbí láti ràn ọ́ lọ́wọ́ ni gbogbo ọ̀nà.

Títúmọ̀-èdè ní kíákíá tí ó sì ṣe déédé sí àti láti àwọn èdè 71

Yíyan ilé-iṣẹ́ atúmọ̀-èdè kan tí ó ṣeé gbáralé tí ó kọ́ṣẹ́mọṣẹ́ fún ìtumọ̀-èdè ìwé rẹ jẹ́ ìpinnu tí ó ṣe pàtàkì. À wa ní CE mọ ṣíṣe pàtàkì níní òye ìtumọ̀ ìfiránṣẹ́ rẹ ní kedere àti ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́. Pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ ẹgbẹ́ atúmọ̀-èdè tí ó kún ojú òṣùwọ̀n tí ó farajìn, à wa ńran àwọn ilé-iṣẹ́, àwọn àjọ àti ilé-iṣẹ́ àti ènìyàn kọ̀ọ̀kan lọ́wọ́ pẹ̀lú ìtumọ̀ sí àti láti àwọn èdè 71. A tí nṣe agbátẹrù ìbáraẹnisọ̀rọ̀ làti ẹgbẹ̀rún ọdún sẹ́yìn.

Fún ilé-iṣẹ́ atúmọ̀-èdè tí ó dára, kọ́kọ́rọ́ọ́ sí àlùyọ ni dídára àwọn atúmọ̀-èdè wọn. Àwọn atúmọ̀-èdè wa nígbà gbogbo jẹ́ àwọn tí ó kún ojú òṣùwọ̀n akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ tí ó wọ́n jẹ́ abínibí tí wọn ńsọ èdè tí a fẹ́ túmọ̀ sí. A yàn wọ́n nítorí ìrírí wọn àti kíkún ojú òṣùwọ̀n ní oríṣirísi àwọn ìpele iṣẹ́ ákànṣe wọn. Ọ̀nà yíyàn wa tí ó ga gan-an máa ńjẹ́ kí iṣẹ́ tí a ńṣe dé èyí tí ẹ ńlérò. À wá wo pípa àṣírí mọ́ àti ìdáàbòbò bíi ìgbẹkẹ̀lẹ́ tí ó sọ̀wọ́n. Gbogbo ìtumọ̀ ni yóò wà ni àṣírí pátápátá.

Ilé-iṣẹ́ tí yóò pàpà di CE ni adásílẹ̀ ní ọdún-un 1999 pẹ̀lú ìgbèsè láti ṣe iṣẹ́ ìtumọ̀-èdè kánkán, tí o ṣeé gbáralé tí o sì rọrùn láti rí ààyè sí. Ọ̀rọ̀ àkọmọ̀nà ilé-iṣẹ́ atúmọ̀-èdè wa ni láti pèsè àwọn ìtumọ̀-èdè tí o dára gan-an ní àkókò. A mọ bí àkókò ti ṣe pàtàkì síí fún àwọn okòwò; àíjafara fún ìṣẹjú díè lè mú àwọn ewu tí o burujai lowo. Fún ìdí èyí CE ṣe ìlérí láti pèsè àwọn ìtumọ̀-èdè tí o tayọ l’akoko àti ni iye owó tí kò ga jù.

Pẹ̀lú CE bíi alábàáṣiṣẹ́ pọ̀ ìtumọ̀-èdè rẹ, o kò ní láti ṣe àníyàn nípa àkókò dídápadà tí ó dára, tàbí owó sísan. À wa ńpèsè ìtumọ̀-èdè tí ó ga gan-an fún àwọn ilé-iṣẹ́ kan, láì kó àwọn oníbàárà sí òfintótó ìṣè, ìṣè pépà, àkókò tí a fi ṣòfò tàbí owò tí ó ti pọ̀jù.

À wa máa ńṣe akitiyan síwájú síi fún dídára, tí a sì máa ńṣe iṣẹ́ kọ̀ọ̀kan ní ìbámu pẹ̀lú àwọn nǹkan tí oníbàárà kọ̀ọ̀kan fẹ́. Ìtara wa fún èdè àti iṣẹ́ dídára, ní àsopọ̀ pẹ̀lú bí a ṣe ńṣe dáradára sí oníbàárà wa tí o tayọ, jẹ́ kí a jẹ́ ààyòò fún gbogbo ìtúmọ̀-èdè rẹ.

Nígbàtí o bá ṣiṣẹ́ pẹ̀lú wa, ẹ̀yin lè ní ìdánilójú gbígba àwọn ìtumọ̀ tí ó tọ́, tí a ó fi ranṣẹ kí àkókò tó tó, àti ní iye owó ìṣúná tí a ṣe àdéhùn. À wa mu dáyin lójú wípé ẹ̀yin yóò ní ìtẹ́lọ́rùn 100% pẹ̀lú gbogbo iṣẹ́ tí ẹ fi sí àkóso wa láti parí.

Awọn gbolohun ọrọ

 • Àwọn ìtánsòro Swídìsh
 • Ìtánsòro Swídìsh rẹ
 • Àwọn alájùmọ̀sọ̀rọ̀ ìsòwò Swídìsh
 • Alájùmọ̀sọ̀rọ̀ ìsòwò Swídìsh rẹ
 • Alábàásepọ̀ ìsòwò Swídìsh
 • Alábàásepọ̀ ìsòwò Swídìsh rẹ
 • Àwọn akọ́sẹ́mọsẹ́ Swídìsh
 • Àwọn akọ́sẹ́mọsẹ́ Swídìsh rẹ
 • Àwọn ọ̀jọ́gbọ́n Swídìsh
 • Àwọn ọ̀jọ́gbọ́n Swídìsh rẹ
 • Àwọn amòye Swídìsh
 • Àwọn amòyé Swídìsh rẹ
 • Àwọn ilé-isẹ́ tó já-fáfá nyan Swídìn
 • Se àwári Swídìn pẹ̀lú wa
 • O nfẹ́ lati s’òwò ni Swídìn?
 • Jẹ́k’á se é ni Swídìn
 • Jẹ gàba lori ọja Swídìsh náà
 • Jẹ́k’á sọ̀rọ̀ nipa Swídìn
 • Ọjọ́ iwájú rẹ ni Swídìn
 • Swídìn, yíyàn tó jáfáfá náà
 • Swídìn, ọ̀nà tó jáfáfá náà
 • Swídìn, ọ̀nà rẹ!
 • Sàseyọrí ni Swídìn
 • Paríparí ìtánsòro Swídìsh náà
 • Àsopọ̀ Swídìsh rẹ
 • Se àseyọrí ni Swídìn
 • Jẹ́ aláseyọrí ni Swídìn
 • Wá àseyọrí ni Swídìn
error: Innehållet är skyddat

CE